Orin Dafidi 58:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ǹjẹ́ ìpinnu tí ẹ̀ ń ṣe tọ̀nà, ẹ̀yin aláṣẹ? Ǹjẹ́ ẹ̀ ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan ní ọ̀nà ẹ̀tọ́?

Orin Dafidi 58

Orin Dafidi 58:1-4