Orin Dafidi 55:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó bá ṣe pé ọ̀tá ní ń gàn mí,ǹ bá lè fara dà á.Bí ó bá ṣe pé ẹni tí ó kórìíra mi ní ń gbéraga sí mi,ǹ bá fara pamọ́ fún un.

Orin Dafidi 55

Orin Dafidi 55:10-15