Orin Dafidi 51:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ṣàánú mi, Ọlọrun, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀;nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ pa ẹ̀ṣẹ̀ mi rẹ́.

2. Wẹ̀ mí mọ́ kúrò ninu àìdára mi,kí o sì wẹ̀ mí kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ mi!

3. Nítorí mo mọ ibi tí mo ti ṣẹ̀,nígbà gbogbo ni ẹ̀ṣẹ̀ mi sì wà níwájú mi.

Orin Dafidi 51