Orin Dafidi 51:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣàánú mi, Ọlọrun, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀;nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ pa ẹ̀ṣẹ̀ mi rẹ́.

Orin Dafidi 51

Orin Dafidi 51:1-11