Orin Dafidi 50:22 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, ẹ fi èyí lékàn, ẹ̀yin tí ẹ gbàgbé Ọlọrun,kí n má baà fà yín ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ, kò sì ní sí ẹni tí yóo gbà yín kalẹ̀.

Orin Dafidi 50

Orin Dafidi 50:16-23