Orin Dafidi 50:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan wọnyi ni ẹ ti ṣe tí mo sì dákẹ́;ẹ wá ń rò ninu yín pé, èmi yín rí bákan náà.Ṣugbọn nisinsinyii mò ń ba yín wí,mo sì ń fi ẹ̀sùn kàn yín.

Orin Dafidi 50

Orin Dafidi 50:11-23