Orin Dafidi 47:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kọ orin ìyìn sí Ọlọrun, ẹ kọ orin ìyìn;Ẹ kọ orin ìyìn sí Ọba wa, ẹ kọ orin ìyìn!

Orin Dafidi 47

Orin Dafidi 47:1-9