Orin Dafidi 47:5 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti gbé Ọlọrun ga pẹlu ìhó ayọ̀,a ti gbé OLUWA ga pẹlu ìró fèrè.

Orin Dafidi 47

Orin Dafidi 47:1-9