Orin Dafidi 44:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan yìí ló ṣẹlẹ̀ sí wa,bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kò gbàgbé rẹ,bẹ́ẹ̀ ni a kò yẹ majẹmu rẹ.

Orin Dafidi 44

Orin Dafidi 44:13-23