Orin Dafidi 44:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ àwọn apẹ̀gàn ati apeni-níjà ṣẹ mọ́ mi lára,lójú àwọn ọ̀tá mi ati àwọn tí ó fẹ́ gbẹ̀san.

Orin Dafidi 44

Orin Dafidi 44:6-24