Orin Dafidi 42:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Omijé ni mo fi ń ṣe oúnjẹ jẹ tọ̀sán-tòru,nígbà tí wọn ń bi mí lemọ́lemọ́ pé,“Níbo ni Ọlọrun rẹ wà?”

Orin Dafidi 42

Orin Dafidi 42:1-4