Orin Dafidi 42:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Òùngbẹ Ọlọrun ń gbẹ ọkàn mi,àní, òùngbẹ Ọlọrun alààyè.Nígbà wo ni n óo lọ, tí n óo tún bá Ọlọrun pàdé?

Orin Dafidi 42

Orin Dafidi 42:1-8