Orin Dafidi 41:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó bá wà ní ìdùbúlẹ̀ àìsàn,OLUWA yóo fún un lókun;ní àkókò àìlera OLUWA yóo wo gbogbo àrùn rẹ̀ sàn.

Orin Dafidi 41

Orin Dafidi 41:1-6