Orin Dafidi 41:10-12 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Ṣugbọn, OLUWA, ṣàánú mi;gbé mi dìde, kí n lè san ẹ̀san fún un.

11. Kí n lè mọ̀ pé o fẹ́ràn mi,nígbà tí ọ̀tá kò bá borí mi.

12. O ti gbé mi ró nítorí ìwà pípé mi,o sì fi ẹsẹ̀ mi múlẹ̀ níwájú rẹ títí lae.

Orin Dafidi 41