Orin Dafidi 39:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Dájúdájú, eniyan ń káàkiri bí òjìji,asán sì ni gbogbo làálàá rẹ̀;eniyan a máa kó ọrọ̀ jọ ṣá,láìmọ ẹni tí yóo kó o lọ.

Orin Dafidi 39

Orin Dafidi 39:1-10