Orin Dafidi 39:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó, o ti ṣe ọjọ́ mi ní ìwọ̀n ìbú àtẹ́lẹwọ́ mélòó kan,ọjọ́ ayé mi kò sì tó nǹkankan ní ojú rẹ;dájúdájú, ọmọ eniyan dàbí afẹ́fẹ́ lásán.

Orin Dafidi 39

Orin Dafidi 39:1-7