Orin Dafidi 36:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ń rí oúnjẹ jẹ ní àjẹyó ní ilé rẹ;nǹkan mímu tí ń ṣàn bí odò,ni o sì ń fún wọn mu.

Orin Dafidi 36

Orin Dafidi 36:7-12