Orin Dafidi 36:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ níye lórí pupọ, Ọlọrun!Àwọn ọmọ eniyan a máa sá sí abẹ́ òjìji ìyẹ́ apá rẹ.

Orin Dafidi 36

Orin Dafidi 36:1-10