Orin Dafidi 35:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, gbógun ti àwọn tí ń gbógun tì mí;gbé ìjà ko àwọn tí ń bá mi jà!

2. Gbá asà ati apata mú,dìde, kí o sì ràn mí lọ́wọ́!

3. Fa ọ̀kọ̀ yọ kí o sì dojú kọ àwọn tí ń lépa mi!Ṣe ìlérí fún mi pé, ìwọ ni olùgbàlà mi.

Orin Dafidi 35