Orin Dafidi 35:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Fa ọ̀kọ̀ yọ kí o sì dojú kọ àwọn tí ń lépa mi!Ṣe ìlérí fún mi pé, ìwọ ni olùgbàlà mi.

Orin Dafidi 35

Orin Dafidi 35:1-8