Orin Dafidi 34:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ bẹ̀rù OLUWA, ẹ̀yin eniyan mímọ́ rẹ̀,nítorí pé kò sí àìní fún àwọn tí ó bá bẹ̀rù rẹ̀!

Orin Dafidi 34

Orin Dafidi 34:1-19