Orin Dafidi 34:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ kinniun a máa ṣe aláìní,ebi a sì máa pa wọ́n;ṣugbọn àwọn tí wọ́n bá ń wá OLUWAkò ní ṣe aláìní ohun rere kankan.

Orin Dafidi 34

Orin Dafidi 34:8-11