Orin Dafidi 33:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wọ́ gbogbo omi òkun jọ bí òkìtì;ó pa gbogbo omi inú àwọn ibú pọ̀ bí ẹni pé ó rọ ọ́ sinu àgbá ńlá.

Orin Dafidi 33

Orin Dafidi 33:6-13