Orin Dafidi 33:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fi gòjé yin OLUWA,ẹ fi hapu olókùn mẹ́wàá kọ orin sí i.

Orin Dafidi 33

Orin Dafidi 33:1-4