Orin Dafidi 33:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe pípọ̀ tí àwọn ọmọ ogun pọ̀ ní ń gba ọba là;kì í sì í ṣe ọ̀pọ̀ agbára níí gba jagunjagun là.

Orin Dafidi 33

Orin Dafidi 33:9-18