Orin Dafidi 32:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa yọ̀ ninu OLUWA;ẹ fò fún ayọ̀, ẹ̀yin olódodo;kí ẹ sì hó fún ayọ̀, gbogbo ẹ̀yin ọlọ́kàn mímọ́.

Orin Dafidi 32

Orin Dafidi 32:8-11