Orin Dafidi 31:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni ẹ̀gàn ni mí láàrin gbogbo àwọn ọ̀tá mi,àwòsọkún ni mí fún àwọn aládùúgbò.Mo di àkòtagìrì fún àwọn ojúlùmọ̀ mi,àwọn tí ó rí mi lóde sì ń sá fún mi.

Orin Dafidi 31

Orin Dafidi 31:2-18