Orin Dafidi 31:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ìbànújẹ́ ni mo fi ń lo ayé mi;ìmí ẹ̀dùn ni mo sì fi ń lo ọdún kan dé ekeji.Ìpọ́njú ti gba agbára mi;gbogbo egungun mi sì ti di hẹ́gẹhẹ̀gẹ.

Orin Dafidi 31

Orin Dafidi 31:4-15