Orin Dafidi 30:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé fún ìgbà díẹ̀ ni ibinu rẹ̀,ṣugbọn títí ayé ni ojurere rẹ̀;eniyan lè máa sọkún títí di alẹ́,ṣugbọn ayọ̀ ń bọ̀ fún un lówùúrọ̀.

Orin Dafidi 30

Orin Dafidi 30:1-7