Orin Dafidi 30:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kọ orin ìyìn sí OLUWA, ẹ̀yin olùfọkànsìn rẹ̀,kí ẹ sì fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ̀.

Orin Dafidi 30

Orin Dafidi 30:3-12