Orin Dafidi 30:10-12 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Gbọ́ OLUWA, kí o sì ṣàánú mi,OLUWA, ràn mí lọ́wọ́.

11. O ti bá mi sọ ọ̀fọ̀ mi di ijó,o ti bọ́ aṣọ ọ̀fọ̀ kúrò lára mi,o sì ti dì mí ní àmùrè ayọ̀,

12. kí ọkàn mi lè máa yìn ọ́ láìdákẹ́.OLUWA Ọlọrun mi, n óo máa fi ọpẹ́ fún ọ títí lae.

Orin Dafidi 30