Orin Dafidi 31:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ìwọ ni mo sá di,má jẹ́ kí ojú tì mí lae;gbà mí, nítorí olóòótọ́ ni ọ́.

Orin Dafidi 31

Orin Dafidi 31:1-8