Orin Dafidi 30:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. N óo yìn ọ́, OLUWA,nítorí pé o ti yọ mí jáde;o kò sì jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi ó yọ̀ mí.

2. OLUWA, Ọlọrun mi, mo ké pè ọ́,o sì wò mí sàn.

3. OLUWA, o ti yọ mí kúrò ninu isà òkúo sọ mí di ààyè láàrin àwọn tíwọ́n ti wọ inú kòtò.

Orin Dafidi 30