Orin Dafidi 29:5-7 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Ohùn OLUWA ń fọ́ igi kedari,OLUWA ń fọ́ igi kedari ti Lẹbanoni.

6. Ó ń mú kí òkè Lẹbanoni ta pọ́núnpọ́nún bí ọmọ mààlúù,ó sì mú kí òkè Sirioni máa fò bí akọ ọmọ mààlúù-igbó.

7. Ohùn OLUWA ń yọ iná lálá.

Orin Dafidi 29