Orin Dafidi 28:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Gba àwọn eniyan rẹ là, OLUWA,kí o sì bukun ilẹ̀ ìní rẹ.Jẹ́ olùṣọ́-aguntan wọn,kí o sì máa tọ́jú wọn títí lae.

Orin Dafidi 28

Orin Dafidi 28:6-9