Orin Dafidi 29:3 BIBELI MIMỌ (BM)

À ń gbọ́ ohùn OLUWA lójú omi òkun,Ọlọrun ológo ń sán ààrá,Ọlọrun ń sán ààrá lójú alagbalúgbú omi.

Orin Dafidi 29

Orin Dafidi 29:1-6