Orin Dafidi 29:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ fún OLUWA ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀,ẹ máa sin OLUWA ninu ẹwà mímọ́ rẹ̀.

Orin Dafidi 29

Orin Dafidi 29:1-5