Orin Dafidi 29:10-11 BIBELI MIMỌ (BM)

10. OLUWA jókòó, ó gúnwà lórí ìkún omi;OLUWA jókòó, ó gúnwà bí ọba títí lae.

11. OLUWA yóo fún àwọn eniyan rẹ̀ ní agbára;OLUWA yóo fún wọn ní ibukun alaafia.

Orin Dafidi 29