Orin Dafidi 28:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé wọn kò ka iṣẹ́ OLUWA sí,wọn kò sì bìkítà fún iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀,OLUWA yóo sọ wọ́n di ilẹ̀,kò sì ní gbé wọn dìde mọ́.

Orin Dafidi 28

Orin Dafidi 28:1-9