Orin Dafidi 28:4 BIBELI MIMỌ (BM)

San án fún wọn gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ wọn,àní gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ burúkú wọn;san án fún wọn gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ọwọ́ wọn,fún wọn ní èrè tí ó tọ́ sí wọn.

Orin Dafidi 28

Orin Dafidi 28:2-9