Orin Dafidi 27:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Má fi mí lé ìfẹ́ àwọn ọ̀tá mi lọ́wọ́;nítorí pé àwọn ẹlẹ́rìí èké dìde sí mi,ètè wọn sì kún fún ọ̀rọ̀ ìkà.

Orin Dafidi 27

Orin Dafidi 27:7-14