Orin Dafidi 27:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Kọ́ mi ní ọ̀nà rẹ, OLUWA,kí o sì tọ́ mi sí ọ̀nà títẹ́jú rẹ,nítorí àwọn ọ̀tá mi.

Orin Dafidi 27

Orin Dafidi 27:7-14