Orin Dafidi 25:15 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ni mò ń wò lójú nígbà gbogbo,nítorí òun ni yóo yọ ẹsẹ̀ mi kúrò ninu àwọ̀n.

Orin Dafidi 25

Orin Dafidi 25:9-22