Orin Dafidi 25:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí ó bá bẹ̀rù OLUWA ni OLUWA ń mú ní ọ̀rẹ́,a sì máa fi majẹmu rẹ̀ hàn wọ́n.

Orin Dafidi 25

Orin Dafidi 25:6-19