Orin Dafidi 21:9 BIBELI MIMỌ (BM)

O óo jó wọn run bí iná ìléru, nígbà tí o bá yọ sí wọn.OLUWA yóo gbé wọn mì ninu ibinu rẹ̀;iná yóo sì jó wọn ní àjórun.

Orin Dafidi 21

Orin Dafidi 21:2-13