Orin Dafidi 20:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìhó ayọ̀ ni a óo hó nígbà tí o bá ṣẹgun,ní orúkọ Ọlọrun wa ni a óo sì fi ọ̀págun wa sọlẹ̀;OLUWA yóo dáhùn gbogbo ìbéèrè rẹ.

Orin Dafidi 20

Orin Dafidi 20:1-9