Orin Dafidi 18:49 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ni èmi ó ṣe máa yìn ọ́ láàrin àwọn orílẹ̀-èdè, OLUWA,èmi ó sì máa kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:41-50