Orin Dafidi 18:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun tí ó gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi;tí ó sì gbé mi ga ju àwọn abínú-ẹni lọ;ìwọ ni o gbà mí lọ́wọ́ àwọn ẹni ipá tí ó dìde sí mi.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:43-50