Orin Dafidi 18:44 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n bá ti gbúròó mi ni wọ́n ń gbọ́ràn sí mi lẹ́nu;àwọn àjèjì ń fi ìbẹ̀rùbojo tẹríba, wọ́n ń wá ojurere mi.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:43-50