Orin Dafidi 18:43 BIBELI MIMỌ (BM)

O gbà mí lọ́wọ́ ọ̀tẹ̀ àwọn eniyan,o fi mí ṣe olórí àwọn orílẹ̀-èdè;àwọn orílẹ̀-èdè tí n kò mọ̀ rí sì ń sìn mí.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:41-44